1 Ọba 15:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bááṣà, ọba Ísírẹ́lì sì gòkè lọ sí Júdà, ó sì kọ́ Rámà láti má jẹ́ kí ẹnikẹ́ni jáde tàbí wọlé tọ Áṣà ọba lọ.

1 Ọba 15

1 Ọba 15:8-22