1 Ọba 14:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níti ìyókù ìṣe Réhóbóámù, àti gbogbo ohun tí ó ṣe, ǹjẹ́ a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba Júdà bí?

1 Ọba 14

1 Ọba 14:23-31