1 Ọba 14:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn tí ń hùwà panṣágà sì tún ń bẹ ní ilẹ̀ náà, àwọn ènìyàn náà sì ṣe gẹ́gẹ́ bí gbogbo ohun ìríra àwọn orílẹ̀ èdè tí Olúwa ti lé jáde kúrò níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

1 Ọba 14

1 Ọba 14:21-31