1 Ọba 14:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì kọ Ísírẹ́lì sílẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí Jéróbóámù ti ṣẹ̀ àti tí ó mú Ísírẹ́lì ṣẹ̀.”

1 Ọba 14

1 Ọba 14:10-23