1 Ọba 13:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí iṣẹ́ tí ó jẹ́ nípa ọ̀rọ̀ Olúwa sí pẹpẹ tí ó wà ní Bétélì àti sí gbogbo ojúbọ lórí ibi gíga tí ń bẹ ní àwọn ìlú Samáríà yóò wá sí ìmúṣẹ dájúdájú.”

1 Ọba 13

1 Ọba 13:31-34