1 Ọba 13:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wòlíì náà sì wí fún àwọn ọmọ rẹ̀ pé, “Ẹ di kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ní gàárì fún mi,” wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀.

1 Ọba 13

1 Ọba 13:18-31