1 Ọba 11:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó tọ Ásítórétì òrìṣà àwọn ará Sídónì lẹ́yìn, àti Mílíkómì òrìṣà ìríra àwọn ọmọ Ámónì.

1 Ọba 11

1 Ọba 11:1-13