1 Ọba 11:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì wá ọ̀nà láti pa Jéróbóámù, ṣùgbọ́n Jéróbóámù sá lọ sí Éjíbítì, sọ́dọ̀ Ṣísákì ọba Éjíbítì, ó sì wà níbẹ̀ títí Sólómónì fi kú.

1 Ọba 11

1 Ọba 11:35-43