1 Ọba 11:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí sì ni ìdí tí ó fi sọ̀tẹ̀ sí ọba: Sólómónì kọ́ Mílò, ó sì di ẹ̀yà ìlú Dáfídì baba rẹ̀.

1 Ọba 11

1 Ọba 11:22-32