1 Ọba 11:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Résónì sì jẹ́ ọ̀ta Ísírẹ́lì ní gbogbo ọjọ́ Sólómónì, ó ń pa kún ibi ti Hádádì ṣe. Bẹ́ẹ̀ ni Résónì jọba ní Síríà, ó sì sòdì sí Ísírẹ́lì.

1 Ọba 11

1 Ọba 11:23-34