1 Ọba 11:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Arábìnrin Tápénésì bí ọmọkùnrin kan fún un tí à ń pe orúkọ rẹ̀ ní Génúbátì, ẹni tí Tápénésì tọ́ dàgbà ní ààfin ọba. Níbẹ̀ ni Génúbátì ń gbé pẹ̀lú àwọn ọmọ Fáráò fún ra rẹ̀.

1 Ọba 11

1 Ọba 11:14-29