1 Ọba 1:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Olúwa ti wà pẹ̀lú Olúwa mi ọba, bẹ́ẹ̀ ni kí ó wà pẹ̀lú Sólómónì kí ó lè mú kí ìjọba rẹ̀ pẹ́ ju ìtẹ́ Olúwa mi Dáfídì Ọba lọ!”

1 Ọba 1

1 Ọba 1:27-44