1 Ọba 1:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lónìí dandan ni èmi yóò gbé ohun tí mo ti fi Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì búra fún yọ pé: Sólómónì ọmọ rẹ ni yóò jẹ ọba lẹ́yìn mi, àti pé yóò jókòó lórí ìtẹ́ mi ní ipò mi.”

1 Ọba 1

1 Ọba 1:29-34