1 Kọ́ríńtì 9:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé àwa kò ní ẹ̀tọ́ láti máa mú ìyàwó tí í se onígbàgbọ́ káàkiri gẹ́gẹ́ bí àwọn Àpósítélì mìíràn? Àti bí arákùnrin Olúwa, àti Kéfà.

1 Kọ́ríńtì 9

1 Kọ́ríńtì 9:1-10