1 Kọ́ríńtì 9:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tó bá jẹ́ pé mò ń wàásù tinútinú mi, nígbà náà Olúwa ní ẹ̀bùn pàtàkì fún mi, ṣùgbọ́n tí ń kò bá ṣe é tinútinú mi, mo ṣe àsìlò ìdanilójú tí a ní nínú mi.

1 Kọ́ríńtì 9

1 Kọ́ríńtì 9:13-20