1 Kọ́ríńtì 7:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ó bá sì jẹ́ obìnrin ló fẹ́ ọkọ tí kò gbàgbọ́, ṣùgbọ́n tí ọkọ náà ń fẹ́ kí obìnrin yìí dúró tí òun, aya náà kò gbọdọ̀ kọ̀ ọ́ sílẹ̀.

1 Kọ́ríńtì 7

1 Kọ́ríńtì 7:11-22