1 Kọ́ríńtì 6:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú agbára rẹ̀, Ọlọ́run jí Olúwa dìde kúrò nínú òkú bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni yóò jí àwa náà dìde.

1 Kọ́ríńtì 6

1 Kọ́ríńtì 6:6-20