1 Kọ́ríńtì 4:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Títí di wákàtí yìí ni a ń rìn kiri nínú ebi àti òùngbẹ, a wọ aṣọ àkísà, tí a sì ń lù wa, tí a kò sì ní ibùgbé kan.

1 Kọ́ríńtì 4

1 Kọ́ríńtì 4:4-15