1 Kọ́ríńtì 16:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹníkẹ́ní kò bá ní ìfẹ́ Jesu Kírísítì Olúwa, jẹ́ kí ó dì ẹni ìfibú. Máa bọ Olúwa wa!

1 Kọ́ríńtì 16

1 Kọ́ríńtì 16:19-24