1 Kọ́ríńtì 15:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ní a si kọ ọ́ pé, “Ádámù ọkùnrin ìṣáàjú, alààyè ọkàn ni a dá a” Ádámù ìkẹ́yìn ẹ̀mí ti ń fún ní ní ìyè.

1 Kọ́ríńtì 15

1 Kọ́ríńtì 15:36-52