1 Kọ́ríńtì 15:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti èyí tí ìwọ fúnrúgbìn, kì í ṣe ara tí ń bọ̀ ni ìwọ fúnrúgbìn, ṣùgbọ́n irúgbín lásán ni, ìbáàṣe àlìkámà, tabi irú mìíràn.

1 Kọ́ríńtì 15

1 Kọ́ríńtì 15:31-41