1 Kọ́ríńtì 15:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ ji ìjí òdodo, kí ẹ má sì dẹ́ṣẹ̀; nítorí àwọn ẹlómírán kò ni imọ̀ Ọlọ́run: mo sọ èyí kí ojú baà lè ti yín.

1 Kọ́ríńtì 15

1 Kọ́ríńtì 15:26-40