1 Kọ́ríńtì 15:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní báyìí, bí kò bá sí àjíǹde, kín ní ète àwọn ènìyàn tí wọn ń tẹ bọmi nítorí òkú? Bí àwọn òkú kò bá jíǹde rárá, nítorí kín ni a ṣe ń bamítíìsì wọn nítorí wọn?

1 Kọ́ríńtì 15

1 Kọ́ríńtì 15:23-30