1 Kọ́ríńtì 15:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí bí gbogbo ènìyàn ti kú nínú Ádámù, bẹ́ẹ̀ ní a ó sì sọ gbogbo ènìyàn dí alààyè nínú Kírísitì.

1 Kọ́ríńtì 15

1 Kọ́ríńtì 15:13-30