1 Kọ́ríńtì 14:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ni? Ṣe lọ́dọ̀ yín ní ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ti jáde ni, tabi ẹ̀yin nìkan ni o tọ̀ wá?

1 Kọ́ríńtì 14

1 Kọ́ríńtì 14:31-40