1 Kọ́ríńtì 13:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìfẹ́ a máa mú sùúrù, ìfẹ́ a máa ṣeun, ìfẹ̀ kì í ṣe ìlara, ìfẹ́ kì í fẹ̀, ìfẹ́ kì í sọ̀rọ̀ ìgbéraga.

1 Kọ́ríńtì 13

1 Kọ́ríńtì 13:2-11