1 Kọ́ríńtì 12:3-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Nítorí náà, èmí ń sọ fún un yín pé kò sí ẹni ti ń sọ̀rọ̀ nípaṣẹ̀ Ẹ̀mí Ọlọ́run tí ó lè wí pé, “Ẹni ìfibú ni Jésù,” àti pé kò sí ẹni tí ó lè sọ pé, “Olúwa ni Jésù,” bí kò ṣe nípàṣẹ̀ Ẹ̀mí mímọ́.

4. Ǹjẹ́ onírúurú ẹ̀bùn ni ó wà, ùgbọ́n Ẹ̀mí kan náà ni.

5. Onírúurú iṣẹ́-ìranṣẹ́ ni ó sì wà, ṣùgbọ́n Ọlọ́run kan náà sì ni.

1 Kọ́ríńtì 12