1 Kọ́ríńtì 11:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdí nìyìí tí ọ̀pọ̀ yín fi di ẹni tí kò lágbára mọ́, tí ọ̀pọ̀ yín sì ń sàìsàn, àwọn mìíràn nínú yín tilẹ̀ ti sùn.

1 Kọ́ríńtì 11

1 Kọ́ríńtì 11:25-34