1 Kọ́ríńtì 11:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bákan náà ló mu kọ́ọ̀bù ọtí wáìnì lẹ́yìn oúnjẹ, ó sì wí pé, “Kọ́ọ̀bù yìí ní májẹ̀mú titun nínú ẹ̀jẹ̀ mi, ẹ máa ṣe èyí, nígbàkígbà ti ẹ̀yìn bá ń mu ú, ní ìrántí mi.”

1 Kọ́ríńtì 11

1 Kọ́ríńtì 11:24-33