1 Kíróníkà 8:18-26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

18. Íṣíméráì, Íṣílíáhì àti Jóbábì jẹ́ àwọn ọmọ Élípálì.

19. Jákímì, Ṣíkírì, Ṣábídì,

20. Élíénáì Ṣílétaì Élíélì,

21. Ádáyà, Béráíáhì àti Ṣímírátì jẹ́ àwọn ọmọ, Ṣíméhì.

22. Íṣípánì Ébérì, Élíélì,

23. Ábídónì, Ṣíkírì, Hánánì,

24. Hánáníyà, Élámù, Ánítótíjáhì,

25. Ífédíà Pénúélì jẹ́ àwọn ọmọ Ṣásákì.

26. Ṣámíséráì, Ṣéháríà, Átalíà

1 Kíróníkà 8