1 Kíróníkà 8:14-21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

14. Áhíò, Ṣásákì Jérémílò,

15. Ṣébádíà, Árádì, Édérì

16. Míkáélì Íṣífà àti Jóhà jẹ́ àwọn ọmọ Béríà.

17. Ṣébàdíáhì, Mésúlámù Hésékì, Hébérì

18. Íṣíméráì, Íṣílíáhì àti Jóbábì jẹ́ àwọn ọmọ Élípálì.

19. Jákímì, Ṣíkírì, Ṣábídì,

20. Élíénáì Ṣílétaì Élíélì,

21. Ádáyà, Béráíáhì àti Ṣímírátì jẹ́ àwọn ọmọ, Ṣíméhì.

1 Kíróníkà 8