1 Kíróníkà 7:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́gbẹ̀ ìpínlẹ̀ ti Mánásè ni Bétí ṣánì, Tánákì, Mógídò àti Dórì lápapọ̀ pẹ̀lú àwọn ìletò Rẹ̀. Àwọn ìran ọmọ Jóṣẹ́fù ọmọ Ísírẹ́lì ń gbé nínú ìlú wọ̀nyí.

1 Kíróníkà 7

1 Kíróníkà 7:26-33