1 Kíróníkà 6:76-79 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

76. Pẹ̀lú láti ẹ̀yà Náfítalìwọ́n gba Kédésì ní Gálílì, Hámoníà Kíríátaímù, lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn.

77. Àwọn ará Mérárì (ìyókù àwọn ará Léfì) gbà nǹkan wọ̀nyí:Láti ẹ̀yà Sébúlúnìwọ́n gba Jókíneámù, Kárítahì, Rímónò àti Tábórì, lápapọ̀ pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko tútù wọn;

78. Láti ẹ̀yà Rúbẹ́nì rékọjá Jódánì ìlà oòrùn Jẹ́ríkòwọ́n gba Bésérì nínú ihà Jáhíṣáhì,

79. Kédémótì àti Méfátù, lápapọ̀ pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko, tútù wọn;

1 Kíróníkà 6