1 Kíróníkà 6:71 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ará Géríṣónítè gbà nǹkan wọ̀nyí:Láti ààbọ̀ ẹ̀yà ti Mánásè wọ́n gba Gólánì ní Básánì àti pẹ̀lú Áṣítarótì, lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù wọn;

1 Kíróníkà 6

1 Kíróníkà 6:63-78