1 Kíróníkà 6:55 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A fún wọn ní Hébírónì ní Júdà pẹ̀lú àyíká pápá oko tútù ilẹ̀ Rẹ̀.

1 Kíróníkà 6

1 Kíróníkà 6:54-64