1 Kíróníkà 6:3-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Àwọn ọmọ Ámírámù:Árónì, Mósè àti Míríámù.Àwọn ọmọkùnrin Árónì:Nádábù, Ábíhù, Élíásérì àti Ítamárì.

4. Élíásérì jẹ́ baba Fínéhásì,Fínéhásì baba Ábísúà

5. Ábísúà baba Búkì,Búkì baba Húṣì,

1 Kíróníkà 6