1 Kíróníkà 4:42-43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

42. Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta nínú àwọn ará Síméónì, sin pẹ̀lú Pélátíà, Néáríà, Réfáíà àti Úsíélì, àwọn ọmọ Íṣì, gbógun sí àwọn òkè ìlú ti Ṣéírì.

43. Wọ́n sì pa àwọn ará Ámálékì tí ó kù àwọn tí ó ti sá lọ, wọ́n sì ti ń gbé bẹ̀ láti òní yìí.

1 Kíróníkà 4