1 Kíróníkà 4:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síméì sì ní ọmọkùnrin mẹ́rìndínlógún àti ọmọbìnrin mẹ́fà, ṣùgbọ́n àwọn ẹ̀gbọ́n Rẹ̀ ọkùnrin kò ní ọmọ púpọ̀; Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ìdílé wọn kò sì pọ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn ènìyàn Júdà.

1 Kíróníkà 4

1 Kíróníkà 4:24-34