1 Kíróníkà 3:17-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

17. Àwọn ọmọ Jéhóíákímù tí a mú ní ìgbékùn:Ṣálátíélì ọmọ Rẹ̀ ọkùnrin,

18. Málíkírámù, Pédáíyà, Ṣénásárì, Jékámíà, Hósámà àti Nédábíà.

19. Àwọn ọmọ Pédáíyà:Ṣérúbábélì àti Ṣíméhì.Àwọn ọmọ Ṣérúbábélì:Mésúlámù àti Hánáníyà,Ṣélómítì ni arábìnrin wọn.

1 Kíróníkà 3