1 Kíróníkà 3:13-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Áhásì ọmọ Rẹ̀,Hesekíáyà ọmọ Rẹ̀,Mánásè ọmọ Rẹ̀,

14. Ámónì ọmọ Rẹ̀,Jósíà ọmọ Rẹ̀.

15. Àwọn ọmọ Jósíà:Àkọ́bí ọmọ Rẹ̀ ni Jóhánánì,èkejì ọmọ Rẹ̀ ni Jéhóíákímù,ẹ̀kẹta ọmọ Rẹ̀ ni Ṣédékíà,ẹ̀kẹ́rin ọmọ Rẹ̀ ni Ṣálúmù.

16. Àwọn ìran ọmọ Jéhóíákímù:Jékóníà ọmọ Rẹ̀,àti Ṣedékíà.

17. Àwọn ọmọ Jéhóíákímù tí a mú ní ìgbékùn:Ṣálátíélì ọmọ Rẹ̀ ọkùnrin,

18. Málíkírámù, Pédáíyà, Ṣénásárì, Jékámíà, Hósámà àti Nédábíà.

1 Kíróníkà 3