1 Kíróníkà 29:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún iṣẹ́ wúrà àti fàdákà náà, àti fún orísìí iṣẹ́ ti ó yẹ ní ṣíṣe nípaṣẹ̀ àwọn tí ó ní òye oríṣíiríṣí iṣẹ́. Níṣinṣìn yìí, ta ni ó ní ìfẹ́ sí yíya ará Rẹ̀ sọ́tọ̀ lónìí sí Olúwa?”

1 Kíróníkà 29

1 Kíróníkà 29:1-6