1 Kíróníkà 29:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tìrẹ Olúwa ni títóbi àti agbára pẹ̀lú ìyìnàti ọlá ńlá àti dídán,nítorí tí gbogbo nǹkan ní ọ̀run àti ayé jẹ́ tìrẹ.Tìrẹ Olúwa ni ìjọba;a gbé ọ ga gẹ́gẹ́ bí orí lórí ohun gbogbo.

1 Kíróníkà 29

1 Kíróníkà 29:6-20