1 Kíróníkà 27:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jónátanì, arákùnrin Dáfídì jẹ́ olùdámọ̀ràn, ọkùnrin onímọ̀ àti akọ̀wé. Jéhíélì ọmọ Hákímónì bojútó àwọn ọmọ ọba.

1 Kíróníkà 27

1 Kíróníkà 27:30-34