1 Kíróníkà 21:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àgọ́ Olúwa tí Mósè ti ṣe ní ihà, àti pẹpẹ ẹbọ ọrẹ ṣíṣun wà lórí ibi gíga ní Gíbíónì ní àkókò náà.

1 Kíróníkà 21

1 Kíróníkà 21:20-30