1 Kíróníkà 2:29-33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

29. Orúkọ ìyàwó Ábísúrì ni Ábíháílì ẹni tí ó bí Áhíbánì àti Mólídì.

30. Àwọn ọmọ NádábùṢélédì àti Ápáímù. Ṣélédì sì kú láìsí ọmọ.

31. Àwọn ọmọ Ápáímù:Isì, ẹnití ó jẹ́ baba fún Ṣésánì.Ṣésánì sì jẹ́ baba fún Áhíláì.

32. Àwọn ọmọ Jádà, arákùnrin Ṣámáì:Jétérì àti Jónátanì. Jétérì sì kú láìní ọmọ.

33. Àwọn ọmọ Jónátanì:Pélétì àti Ṣásà.Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Jéráhímẹ́lì.

1 Kíróníkà 2