1 Kíróníkà 16:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì fi Ṣádókù àlùfáà àti àwọn àlùfáà ẹlẹgbẹ́ Rẹ̀ níwájú Àgọ́ Olúwa ní ibi gíga ní Gíbíónì.

1 Kíróníkà 16

1 Kíróníkà 16:33-43