1 Kíróníkà 14:4-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Èyí ni orúkọ àwọn ọmọ náà tí wọ́n bí fún un níbẹ̀: Ṣámúyà, Ṣóbábù, Nátanì, Ṣólómónì,

5. Íbárì, Élíṣúà, Élífélétì,

6. Nógà, Néfégì, Jáfíà,

7. Élísámà, Bélíádà, àti Élífélétì.

8. Nígbà tí àwọn ará Fílístínì gbọ́ pé a ti fi àmì òróró yàn Dáfídì ní ọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì, wọ́n sì lọ sókè pẹ̀lú ipá láti wá a rí, ṣùgbọ́n Dáfídì gbọ́ nípa Rẹ̀ ó sì jáde lọ láti pàdé wọn.

9. Nísinsìn yìí àwọn ará Fílístínì ti wá láti gbógun ti àfonífojì Réfáímù;

1 Kíróníkà 14