1 Kíróníkà 11:38-44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

38. Jóẹ́lì arákùnrin NátanìMíbárì ọmọ Hágárì,

39. Ṣélékì ará Ámónì,Náháráì ará Bérótì ẹni tí ó jẹ́ áru ìhámọ́ra Jóábù ọmọ Ṣérúyà.

40. Írà ará Ítírì,Gárébù ará Ítírì,

41. Húríyà ará HítìṢábádì ọmọ Áháláyì.

42. Ádínà ọmọ Ṣísà ará Réúbẹ́nì, ẹni tí ó jẹ́ ìjòyè ará Réubẹ́nì, àti pẹ̀lú ọgbọ́n Rẹ̀.

43. Hánánì ọmọ Mákà.Jóṣáfátì ará Mítínì.

44. Úsíà ará Ásílérátì,Ṣámà àti Jégiẹ́lì àwọn ọmọ Hótanì ará Áróérì,

1 Kíróníkà 11