1 Kíróníkà 1:24-31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

24. Ṣémù, Árífákásádì, Sẹ́bà,

25. Ébérì, Pélégì. Réù,

26. Ṣérúgì, Náhórì, Térà:

27. Àti Ábúrámù (tí ń ṣe Ábúráhámù).

28. Àwọn ọmọ Ábúráhámù:Ísáákì àti Íṣímáẹ́lì.

29. Èyí ni àwọn ọmọ náà:Nébáíótì àkọ́bí Íṣímáẹ́lì: Kédárì, Ádíbélì, Míbísámù,

30. Míṣímà, Dúmà, Másà, Hádádì, Témà,

31. Jétúrì, Náfísì, àti Kédámù. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Íṣímáẹ́lì

1 Kíróníkà 1