21. Hádórámì, Úsálì, àti Díkílà
22. Ébálì, Ábímáélì, Ṣébà.
23. Ófírì, Háfílà, àti Jóbábù. Gbogbo àwọn wọ̀nyí sì jẹ́ àwọn ọmọ Jókítanì.
24. Ṣémù, Árífákásádì, Sẹ́bà,
25. Ébérì, Pélégì. Réù,
26. Ṣérúgì, Náhórì, Térà:
27. Àti Ábúrámù (tí ń ṣe Ábúráhámù).
28. Àwọn ọmọ Ábúráhámù:Ísáákì àti Íṣímáẹ́lì.